EDE YORUBA ALAKOOBERE BOOK 5

2,750.00

Yinka Folorunso, Dipo Gbenro, Funmke Ogunsipe, Adebisi Amoo

Year Published: 1994

Page extent: 64pages

Size: 203mm x 260mm

ISBN: 978-978-153-223-8

Revised Edition, 2015

Description

Ede Yoruba Alakoobere je iwe ti a ko ni ibamu pelu Korikuloomu tuntun ti ijoba Apapo fowo si fun lilo ni ile-Iwe Alakoobere ni Orile ede Naijiria.

Awon onkowe wonyi je onimo kikun ninu Eko Ede Yoruba ni afikun imo won gege bi oluko ni ile-iwe akekoo-oluko. Kiko iwe yii tun se pataki nitori akitiyan Ijoba Apapo, ati ipinle ati ti  ibile lori fifi ede abinibi ko omo nile-iwe.

Eleyii yoo mu irorun wa lori kiko ede Yoruba ati fifi ede Yoruba ko omo ni eka eko yooku ti oyato si Yoruba.

Egba ayewo. Ire o

Reviews

There are no reviews yet.

Be the first to review “EDE YORUBA ALAKOOBERE BOOK 5”